ABUL FATHI FORUM
Inú bí ẹ̀fúùfùlẹ̀lẹ̀, ó wó igi lu omi,
Inú bí omi, ó gbé igi lọ. Ìbínú kò mọ̀ pé, olówó òun kò l’ẹ́sẹ̀ n’ílẹ̀. Ìbínú ló n múni yọ idà nínú àkọ̀, ìtìjú ló n múni bẹ́ẹ. Ẹni tí inú n bí tó fa àdá yọ, tó bẹ́ ọmọlakejì rẹ̀ lórí, ṣé tí inú rẹ̀ bá rọ̀, ṣé yíó dá ori míràn padà s’ọ́rùn rẹ̀ ni. Inú àbíjù máa n jékí ire ènìyàn o jìnnà síi ni. Inú ló bí bàbá,tó sọ fún ọmọ rẹ wípé, òun o kìí ṣe ẹgbẹ́ rẹ̀, bi kò ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ, gbogbo ayé ló mọ̀ pé, kékeré kọ́ ní bàbá fi ju ọmọ rẹ̀ lọ. àbọ̀ omi tó n da olówó rẹ̀ láàmú. Inú burúkú ní oogùn òṣì. Ìpọ̀nrí Aláṣọ méjì tó n ránṣẹ sí onípààrọ̀, ọgbọ́n àti rin hòòhò, ló n dá. Ẹni bá tí n bínú jù, kò má ṣiṣẹ́ mọ́,
torípé, isẹ́ tí o fi ojú ọwọ́ ṣe, ẹyìn ọwọ́ ní yíó fi dáa nù. Lóòtó ọmọ alè ènìyàn ló n rínú ti kii bi. Ṣùgbón, inú àbíjù, wèrè lo n sọni dà. Ìwà jẹ́jẹ́ pẹlu sùúrù la lè fi lo ilé ayé ni ìrọ̀rùn.
Inú buruku kò ní bí ọ. O kò níí f'ọwọ́ ara rẹ ṣe ara rẹ lasẹ Èdùmàrè. A kú isinmi oni.
21/04/2020
This thread is for lovers of nature when it comes to health and other areas of our lives.
Prayers are invisible,
but they make impossible
things possible.
It is Allah’s
job to work the wonders.
Our part is simply to pray.
28/02/2018
We All Have Dreams.
But In Order To Make Dreams
Come Into Reality,
It Takes An Awful Lot Of
Determination, Dedication, Self-discipline.
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the school
Telephone
Website
Address
Offa