Temitope alade
11/09/2023
Happy Birthday To ME TEMITOPE ALADE BABA OSHA 1❤️🥰
May All Irumole And Igbamole Be With Me
Ase! Ase!! Ase!!!
I Wish Myself Happy Birthday Once Again.
Olúbó
Àsàbó
Òbòbòtiribò
Ifámojé-Kín-bósonù Lówó Re
Ifá Ní Edan Ni Mí
Edan Kiku
Ki Edan To Gbógbógbó,Ki Edan To Yóyóyó,Ki Edan Tó Kú Bi Okinni Aberé
Àwon Irá Ti Mo Bàsè Won Atikú Tán
Awon Ìwàrè-ìwàrè Ti Mo Básè Won Ati Gbòru Lobi Isu
Kíkú Tóyíkàn Mí Ojó Pé
Odù Kòkò Mejì,Won Ki Yíwon Kan Ara Won
Ewé Gbégbé Lóní Ki Mo Báwon Gbélé Ayé Pé Títií
Ifá Mómò Je Nkú Laitigbo
Roko-Roko Ki Romo Orósè Bi Omo-Eku Gbogbo
Owó Mi Wa Ba Ewé Elésó-ésó Oko
Èsò Ni Kinse Yun,Èsò Ni Kin Sebò
Èsò Ni Kinse Sùn,Èsò Ni Kin Sejí
Èjìogbè Kogbe Ibi Fo Lórí Mi
Òyèkú Méjì Koyeku Lórí Mi
Tóbá Yè Lórí Mi,Móyè Lori Òtá Mí...........
29/06/2023
May Allah give us everything that We desires with the blessings of almighty Allah 🤲may Allah bless us with good health ,wealth and happiness on our ways on this special today and everyday
Blessings will be bestowed upon us on this Eid day🙏💫
Alhamdulilah it is a rea*on to cheerful in every way 🤲Happy Eid Mubarak to all Muslim 👳and muslimat🧕 many more to witness Bihi’dnillah🙏✨💫💫❤️❤️
Temitope Alade Baba Osha cares
10/09/2021
*IMUNLE AWON AGBA TIO YARA SISE KIAKIA BI OGUN OWO FUN ENIKENI NI ETO YI*
*MOSE NI IJETA PELU OJE OKAN LARA AWON* *ETO TIMO NIFE SI PELU SISE RE TELEDUA SI FI* *ASE SI NIGBOGBO IGBA IDAWOLE RE*
Ao ra eiye kowe olori dudu kan, eiye atata kan obi adie funfun balawu kan, oju ologbo pupo, atare odindi nla kan, ao mu atare yen sinu ape ijogun larin meji ape yen, ao fi enu kowe yen gun atare yen larin, ao tun fi enu eiye atata yen naa gun atare yen gegebi igba ti won fe jijo mu omi ninu ikoko kan, ao je ki won koju si ara won, ao wa da oju ologbo pupo yen le won lori ti ara won koni han sita rara, ao jo dada, ti a ba fe so kuro lori ina, ao ni gbe sokale si ilele o, ori nkan meji ni ao so le lori, a le so le idi odo ati nkan omiran, ao wa gbe olo ti ao fi lo le won lori, ao lo kunna dada, ao ro ebu yen sinu ado ato, ao pa obi adie yen, ao fi eje adie yen yi ara ado ato yi, ao wa tu iye abe apa adie yen apa otun ati osi ati iye aya adie yi, ao lemo ara ado ato yi, ao fi ko sibikan ale gbe sinu a*o funfun karan bi apo agbeko ao gbodo je ki o kanle mo, Omi aye ni ao fi ma lo ebu yi laro kutu ki a to soro si enikankan rara
Ona ala gidi kosi enitikole lo ati teka teka oni ise owo ki oni idayan loun ero olowo abo gidi opari
Ajefunyin
Fun ti ipalemo ojo ibimi lola 11/09
*🌲Lati owo emi temitope alade baba osha 🌳*
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the practice
Telephone
Website
Address
Oladeji, Olukotun Street Off Ijegun Ikotun Road �
Lagos