Kini ife
12/04/2024
Iranlowo eda
Baba olowo kan ni Olorun da lola lopolopo kosi ohun tonfe ti Oluwa kose fun, kosi eniyan to sunkun wole baba olowo yi ti koni rerin jade, opo eniyan loyi baba olowo yi ka gegebi emi ati eyin semo pe bi eda kan bani iru owo bayi aimoye opo eniyan ni yio ma feran re lati basepo gbogbo eda lo feran baba olowo tori owo towa lowo re
Ni Ojo kan baba olowo lo si ibi inawo kan, nigba tode ibe o ba awon alfa nibe ti won se waasi lowo, alfa yi sope gbogbo eda pata lo nidi kan ti o fi wa si aye bi Olorun seda olowo lati ran talika lowo be na ni Olorun gbe talika dide lati se iranlowo fun olowo, oro yi ni baba olowo yi gbo tofi binu kuro ni ibi inawo na, botile jepe kosi eda tomo idi pataki ti baba yi fi kuro nibe
Nígbàtí o de ile o bi Iyawo re lere pe kini nkan ti Olorun kose fun mi na Iyawo ni kosi, o bi omo re pe kini nkan ton jemi niya abi tole jemi niya lola omo na dahun pe kosi tori pe e ti sise ojo ola yin ati ojo ola awa na sile fun idi eyi kosi ohun kan tole je yin niya lailai, baba olowo sope nje elero pe mo le nilo iranlowo talika bi, gbogbo awon ebi re dahun pe lailai kole possible kosi iranlowo kan ti talika fese fun yin ayafi ki e yin gan tun se fun won, Baba olowo se alaye fun awon ebi re o je koye awon ebi re pe lati wakati yi lo mio fe ri alfa kankan ninu ile mi lati oni lo, o si wonu ile re lo pelu ibinu
Ojo gori ojo ola baba yi n po si ibukun baba yi posi, okiki baba yi po si Sugbon lojo kan isele nla kan sele. (Next page)
Oni fi ojo oni re ba ojo iwaju re je. Alagbara eniyan toti rope iwalaye re kole wulo fun Iran ohun iru alagbara be ko pada toro ounje je lowo re aseyori re ko soju ota re, aku ola jimoh oloyin toni Koni je asemo funwa amin
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Website
Address
43, Town Planning Way, Ilupeju, Lagos.
Lagos
+234