Eyes Open Event.OK
31/08/2022
Photo Of Fela Rocking Burna Boy’s Mother On Stage Surface » Popup9ja.com Photo Of Fela Rocking Burna Boy’s Mother On Stage Surface. A photo of legendary Nigerian Afrobeat singer Fela Kuti with one of
22/08/2022
Mike Tyson 🗣️"Joshua needs to learn to get away from his (Usyk's) jab because that's the one thing he couldn't handle - his jab and his movement, he was too fast for Joshua. So Joshua has to put a lot of pressure on him and keep that going all night. He's a powerful puncher but he's got to be active against a guy like that. He moves too much, his jab is educated and Joshua needs to just outsmart the guy."
22/08/2022
GBOGBO NAIJIRIA LO WA O!!!
A kuu amojuba ose tuntun yii o, ose ayo ati idunnu ni yoo je fun gbogbo wa. Iwe iroyin yin, YORUBA TOOTO ti bale gude s'ori ate o. Nje e mo awon to gbabode fun Oloye Sunday Igboho l'ojosi ti won kolu ile re n'Ibadan? Bawo ni Igboho se bo mo awon agbofinro l'owo l'ojo naa gan-an? Se ominira Yoruba yoo si see se? E ka awon asiri nla-nla ti Omooba Ademola Omiyale ti won mu n'ile Igboho l'ojo isele naa tu.
Ki l'otito ohun to sele ninu ipade Oloye Olusegun Obasanjo ati Asiwaju Bola Tinubu l'ose to koja? Nje e mo pe won le Gomina Dapo Abiodun, Otunba Gbenga Daniel, Oloye Femi Otedola at'awon mi-in jade? Ki lo de ti won le won jade? Nje eyin mo iha ti egbe Afenifere ko si oro ominira ile Yoruba? Ki lo de ti egbe Afenifere wo koko mo oro atunto ofin Naijiria? E ka asiri ti agbenuso egbe Afenifere, Komureedi Jare Ajayi tu.
Haba! Won ma ni Seneto Ibikunle Amosun ri Awujale Ijebu fin o. Bawo l'Amosun se ri Kabiyesi fin? Paga! Toyin Aimakhu onitiata ma ti wo Liz Anjorin onitiata egbe re lo tesan Olopaa o. Ki lo gbe won debe? Kin ni won ba bo l'odo awon Olopaa? Awon oniroyin ma n mura lati ba Aare Buhari fa wahala o. Iru wahala wo? Ki lo pa oniroyin ati Buhari po?
Eyin araalu Remo eti yin meloo? E waa wo "Erujeje" to wo Remo to n pa awon obinrin l'eyin to ba f'ipa ba won sun tan. Oni l'oni n je! E ka bi igbejo oro idibo yoo se w'aye l'aarin Gomina Gboyega Oyetola t'ipinle Osun ati Seneto Ademola Adeleke. Ki lo de ti won kolu iyawo Oyetola l'Ede? Iru kileyi? E wo b'awon eeyan se te ara won pa ninu gbajumo soosi kan l'Ekoo. Soosi wo? Adugbo wo lo wa? Ki lo de ti won te ara won pa?
E ka ekunrere awon iroyin yii at'awon mi-in pelu awon abala akagbadun ninu iwe iroyin YORUBA TOOTO to jade l'ose yii. Tete loo ra tie nibikibi l'orile-ede yii pelu igba naira pere. YORUBA TOOTO - Agbenuso omo kaaaro-oojiire!!!
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Lagos