Asejere
29/03/2025
Asiko yii lo yẹ kawa ọmọ Yoruba ṣatilẹyin fun Tinubu, o gbọdọ lọ lẹẹkan si i - Bamigboye - Àṣejèrè …Irin ajo oṣelu o rọrun rara, ẹẹmẹta ni mo dije sile aṣofin Eko Lara awọn ijọba ibilẹ to ti pẹ lorile-ede Naijiria nijọba ibilẹ Mushin, awọn alaga to ti jẹ tẹlẹ nibẹ si ṣe daadaa ṣugbọn ara ọtọ ni ti Ọnarebu Emmanuel Bamigboye to n ṣakoso kansu na...
14/05/2024
https://www.asejere.net/gomina-ademola-adeleke-naa-ti-joye-aṣiwaju/
Gomina Ademọla Adeleke naa ti joye Aṣiwaju - Àṣejèrè Gbogbo eto lo ti to bayii lati fi Gomina ipinlẹ Ọṣun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke, jẹ Aṣiwaju ilu Ẹdẹ, lọjọ Aje, Mọnde, ọjọ Aje, ọjọ kẹtala, oṣu Karun-un ọdun yii. Ifijoye yii lo ṣe wẹku pẹlu ayẹyẹ ọjọọbi ọdun kẹrinlelọgọta ti Adeleke dele a...
14/05/2024
https://www.asejere.net/e-wo-iye-tileeṣe-yinka-folawiyo-pa-wole-feko-lori-epo-robi/
E wo iye tileeṣẹ Yinka Fọlawiyọ pa wọle f'Eko lori epo rọbi - Àṣejèrè Iroyin ti te wa lowo pe ogorun milionu naira lo din ninu bilionu merin naira (N3.911bn) ninu iye owo ti ipinle Eko ti pa wole lori ida metala owo to ye ki won maa gba lori epo robi. Bee o ba gbagbe, odun 2016 nipinle Eko darapo mo awon ipinle ti won n gba lowo […]
14/05/2024
https://www.asejere.net/ofin-to-maa-fiya-je-awon-to-n-wa-yanrin-lona-aito-maa-jade-laipe-alebioṣu/
Ofin to maa fiya jẹ awọn to n wa yanrin lọna aitọ maa jade laipẹ - Alebioṣu - Àṣejèrè Ijoba ipinle Eko n se eto lowo lati fofin de awon to n wa yanri lona aito latinu osa nipinle naa. Komisanna to bojuto idagbasoke awon etido nipinle naa, iyen Minisitry of Waterfront Infrastructure Development (MWID), Onarebu Yacoob Ekundayo Alebiosu, ti gbogbo eeyan mo si Dayo Bush lo soro yii di mi...
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Lagos
23401