BaBa ASEYORi

BaBa ASEYORi

Share

Photos from BaBa ASEYORi's post 12/01/2026

LATI DEENA AISAN JEJERE
(TO PREVENT CANCER)
JEJERE je Ipenija Aisan nla ti o Lagbara gidi gan, bee orisirisi Aisan JEJERE ni o wa, Sugbon Mofi olohun Oba bura, ti Eniyan ba nlo Egbogi yi gege bi mose se awon alaye re, Eni na koni bawon ni Aisan na rara.

Ninu awon Iwadi imo ijinle, won jeki o di mimo fun wa pe Lara awon Aisan Ti Eniyan le jogun (Hereditory) ni Aisan JEJERE wa, eyi tumo si wipe, Aisan/Arun a ma to Iran.

Awon ohun ti ao wa
•Ewe Aganho Tutu
•Epo Aganho Tutu
•Egbo Aganho Tutu
•Ako Kahun die

Bi aosese
Ao fi omi fo awon Eronja yi ki o mo dada, ao wa se ki o jina dada fun bi ogbon iseju (30min), ki a se (filter), ki a to sinu Ike ti o bamo.

LILO re
Mimu ni Gass cup kan ni owuro ati ale

Gbogbo wa konifi Aisan logba oo 🙏🏾

Iwo na bami share re, fun Anfani awon Elomiran

Ire oo

Want your practice to be the top-listed Clinic in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address


Lagos