ebman.com.ng

ebman.com.ng

Share

22/07/2024

NO MATTER THE SITUATION I WILL REJOICE IN THE LORD. BECAUSE THE JOY OF THE LORD IS MY STRENGH.

Habakkuk 3:17-19
[17]Bi igi ọpọ̀tọ kì yio tilẹ tanná, ti eso kò si ninu àjara; iṣẹ igi-olifi yio jẹ aṣedanù, awọn oko kì yio si mu onje wá; a o ke agbo-ẹran kuro ninu agbo, ọwọ́ ẹran kì yio si si ni ibùso mọ:
Although the fig tree shall not blossom, neither shall fruit be in the vines; the labour of the olive shall fail, and the fields shall yield no meat; the flock shall be cut off from the fold, and there shall be no herd in the stalls:
[18]Ṣugbọn emi o ma yọ̀ ninu Oluwa, emi o ma yọ̀ ninu Ọlọrun igbàla mi.
Yet I will rejoice in the LORD, I will joy in the God of my salvation.
[19]Oluwa Ọlọrun ni agbara mi, on o si ṣe ẹsẹ̀ mi bi ẹsẹ̀ agbọ̀nrin, lori ibi giga mi ni yio si mu mi rìn. Si olori akọrin lara ohun-ọnà orin olokùn mi.
The LORD God is my strength, and he will make my feet like hinds' feet, and he will make me to walk upon mine high places. To the chief singer on my stringed instruments.

Want your public figure to be the top-listed Public Figure in Ikare-Akoko?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Category

Telephone

Address


Cj/19 Jubilee Road
Ikare-Akoko
234