IFE OKAN MI.
01/12/2021
Mase se iyemeji lori eniti ohun fe! Gbadura fun oko re ololufe re ni ojo owuro kutukutu! Adara fun o Amin!
Ba ololufe re soro itunu, inu re adun si e
13/10/2020
😎😂SE ENIKENI NI MO LE FE. Gbogbo bata ko lo le ba e lese mu, bee naa si ni gbogbo awon to o n ba pade o le je oko tabi aya rere e. Ko o baa le dahun ibeere to gbeyin yen, fara bale ronu nipa eni to o ni lokan lati fe. Amo ko o sora o, Ko ma lo je pe ohun to o fe ri nikan ni waa maa ri. Tori naa, fara e bale. Gbiyanju lati mowa eni naa daadaa. Iyen si maa beere pe ko o sapa gidigidi. Ko ye kiyen ya e lenu da o. Apeere kan ree, Je ka so pe o fe ra oko ayokele kan. Nje o o ni ye oko ayokele naa wo daadaa. Abi bo ba daa ti daa loju, o pari naa niyen. Nje ko ni bogbon mu pe ko o ye e wo tinu teyin, ko o si tun wo bi enjinni e se n sise si paapaa. Wiwa eni teeyan maa fe gbege ju rira oko ayokele lo. Sibe, oju lasan lopo awon to n wa eni ti won maa fe n wo. O maa n ya won lara lati so ohun ti won jo feran. ADOLA😇😍
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Telephone
Website
Address
Challenge
Ibadan