Redemption prayer GROUP
25/12/2019
I PRAY FOR WHOEVER THAT TYPE AMEN HERE,
BY NEST YEAR MY GOD WILL TURN ALL YOUR PRAYER TO POINT TO TESTIMONY IN JESUS NAME..
19/12/2019
IWO NI KI ORI PE O SE AMIN,
MO RI NINU ISELE ALAGBARA TI O SELE SI AWON OMO ISRAEL NIWAJU FARAHO,EMI O MON PE OKUN O GBUDO SI LASAN,LA FI AWON KAN SE ETUTU,
HAMANI TI PINU FUN MODEKAI ,
BENI OLORUN NAN TI PINU RE FUN
AS BI ENIKAN BA MA DIDE ENI NI YIO FI ARA RE SE OHUN ETUTU,
(2) MO GBA ADURA FUN O LONI YI OTA IRE RE DI ETUTU FUN IGBE DIDE RE LONI N'ORUKO JESU,
2)MO WI LONI OHUN GBOGBO TI O PE NI OGUN AYE RE LONI DE ATEGUN RE LONI ,
(2)LATI ONIYI LO GBOGBO ENI TI O JA EMI ATI IWO NI OLE OGO ORUN MUN WON PA LOKOKAN
N'ORUKO JESU.
OHUN
18/12/2019
ORO OLORUN WIPE,
NI IGBA TI A DA IKOLO SIONI PADA WON DA BI ENI TI LA ALA,
LONI OHUN GBOGBO TI OGUN TI GBA LO LAYE EMI ATI IWO ORUN DA WON PADA
N'ORUKO JESU.....
11/12/2019
MO WI GEGE BI WOLI OLORUN LONI,
BI OLORUN BA SI UN GBO TI AWO WOLI R,
TI WOLI OLORUN BA SI KU LAYE LOTO,
LONI LONI LONI,ORUN IRANLOWO PELU IGBE DIDE SI FUN GBOGBO ENI TI O SE AMIN YI TI O SHARE ADURA YI
N'ORUKO JESU....
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Website
Address
Ojoo Express Road Amuda Ojere Iwo Road Area Ibadan
Ibadan