Esimedia TV

Esimedia TV

Share

08/01/2025

LEREFE HEADLINES JAUNUARY 8TH, 2025
1. ÀWON OLÙFÈYÌNTÌ OLÓGUN SE ÌWÓDE LÁNÀ NÍ ÌLÚ ÀBÚJÁ.

2. GÓMÌNÀ DÀPÒ ABÍÓDÚN BÁ EBÍ CASH MADAM KÉDÙN.

3. ILÉ EJÓ GÍGA SÚN EJÓ WÒLÍ NAOMI SÍLÈKÙNÒLÀ ATI ÀWON ÌYÓKÙ RÈ.

4. ÀJÒDÚN ÌGBÉYÀWÓ ÌLÚMÒÓKÁ ÒSÈRÉ SEUN JIMOH.

5. ÌLÚMÒÓKÁ ADÉRÍNPÒSÓNÚ WÒLÍ ÀRÓLÉ BÈBÈ FUN ÌRÀNLÓWÓ.

6. OMO OLÓRIN TAIWO CURRENCY KÉKÒ GBOYÈ.

7. ÀMÒRÀN ALAYOMELODYSINGER SI ÀWON OLÓLÙFÉ RÈ.

--------------------------------------------------------
Kindly follow our social handle to stay update .
Watch the full video in our YouTube channel through our bio

06/01/2025

IROYIN LEREFE JANUARY 6TH 2025

1. ÌJOBA PARAPÒ LÁTI DÁRÒ AKÒWÉ ÌJOBA ÌPÍNLÈ ONDO.

2. ÀÀJO NAFDAC KÉDE AYÉDÈRÚ OÒGÙN ÀRÙN JEJERE.

3. ILÉ ISÉ AYÁNI LÓWÓ ÈLÉ GBÉ ÀWÒRÁN ÀWON ONÍ GBÈSÈ SÍTA.

4. CUBANA CHIEF PRIEST SE ÌLÉRÍ ÒMÌNIRA FÚN SPEED DARLINGTON.

5. ÀDÚRÀ ÌKÍNI ODÚN BUKUNMI OLUWASHINA SÍ ÀWON OLÓLÙFÉ RÈ.

6. BLESSING CEO SO NÍPA ÒRÒ ÌFÉ RÈ PÈLÚ IVD.

7. BÀBÁ WÒLÍÌ ÀRÓLÉ SE ALÁÌSÍ.
------------------------
Kindly follow our social handle to stay update .
Watch the full video in our YouTube channel through our bio

11/11/2024

Bringing to your view your favourite celebrity profiles. Get to know their journey, what they love, do and their current status.
Don't forget to like, comment, share, follow and turn on the notification bell to be the first to know whenever we post a new video.
Also follow us on Instagram

NOTE: We do not own any copyright to any music used.

24/08/2024

ABULECTIC CONCERT; Embrassing our cultural heritage

Want your business to be the top-listed Media Company in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address

HOMERTON Road
Lagos
E95RS